Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 30:35-38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

35. ṣe tùràrí olóòórùn dídùn tí a pò, iṣẹ́ àwọn olóòórùn, tí ó ní iyọ̀, ó dára, ó sì jẹ́ mímọ́.

36. Ìwọ yóò sì lọ díẹ̀ nínú rẹ̀ kúnná, ìwọ yóò sì gbé e ṣíwájú ẹ̀rí ní àgọ́ àjọ, níbi tí èmi yóò ti pàdé yín. Yóò sì jẹ́ mímọ́ jùlọ fún yín.

37. Ẹ má ṣe se tùràrí kankan ní irú èyí fún'ra yín; ẹ kà á ní mímọ́ sí Olúwa.

38. Ẹnikẹ́ni tí ó bá se irú rẹ̀ láti máa gbádùn òórùn rẹ̀, òun ni a ó gé kúrò nínú àwọn ènìyàn rẹ̀.”

Ka pipe ipin Ékísódù 30