Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 30:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ yóò mú ààyò tùràrí olóòórùn sí ọ̀dọ̀ rẹ; ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta sékélì (kílógíráámù mẹ́fà) tí òjíá sísàn, ìdajì bí ó bá yẹ àádọ́tàlérúgba (250) sékélì tí kínámónì dídùn, àti kane dídùn àádọ́tàlérúgba (250) sékélì,

Ka pipe ipin Ékísódù 30

Wo Ékísódù 30:23 ni o tọ