Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 30:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn olówó kì yóò san ju ìdajì sékélì lọ, àwọn talákà kò sì gbọdọ̀ dín ní ìdajì sékélì nígbà tí ẹ̀yin bá mú ọrẹ wá fún Olúwa láti se ètùtù fún ọkàn yín.

Ka pipe ipin Ékísódù 30

Wo Ékísódù 30:15 ni o tọ