Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sì ti sọ̀kalẹ̀ wá láti gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn ará Éjíbítì, àti láti mú wọn gòkè kúrò ní ilẹ̀ náà lọ sí ilẹ̀ tí ó dára tí ó sì ní ààyè, àní ilẹ̀ tí ó ń sàn fún wàrà àti oyin; ibùgbé àwọn ará Kénánì, Hétì, Ámórì, Pérésì, Hífì àti Jébúsì.

Ka pipe ipin Ékísódù 3

Wo Ékísódù 3:8 ni o tọ