Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 3:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn obìnrin ni ó ní láti béèrè lọ́wọ́ àwọn aládùúgbò wọn àti gbogbo àwọn obìnrin ti ń gbé nínú ilé rẹ fún ohun Sílífà àti wúrà àti fún aṣọ, èyí ti ẹ̀yin yóò wọ̀ sí ọrùn àwọn ọmọ yín ọkùnrin àti obìnrin. Báyìí ni ẹ̀yin yóò sì kó ẹrù àwọn ará Éjíbítì.”

Ka pipe ipin Ékísódù 3

Wo Ékísódù 3:22 ni o tọ