Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 3:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lọ, kó àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì jọ, kí o sí sọ fún wọn, ‘Olúwa Ọlọ́run Jákọ́bù; yọ sí mi, ó sì wí pé: Lóòótọ́ èmi ti ń bojúwò yín, èmi sì ti rí ohun tí wọ́n ṣe sí i yín ni ilẹ̀ Íjíbítì.

Ka pipe ipin Ékísódù 3

Wo Ékísódù 3:16 ni o tọ