Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 28:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ yóò sì dá ẹ̀wù àwọ̀tẹ́lẹ̀, ọ̀já àmùrè àti ìgbàrí fún àwọn ọmọ Árónì, láti fún wọn ní ọ̀ṣọ́ àti ọlá.

Ka pipe ipin Ékísódù 28

Wo Ékísódù 28:40 ni o tọ