Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 28:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó wà níwájú orí Árónì, kí ó sì lè máa ru ẹ̀bi tí ó jẹ mọ́ ẹ̀bùn mímọ́ ti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ti yà sí mímọ́, èyíkéyìí tí ẹ̀bùn wọn lè jẹ́. Yóò máa wà níwájú orí Árónì nígbà gbogbo, kí wọn lè jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà fún Olúwa.

Ka pipe ipin Ékísódù 28

Wo Ékísódù 28:38 ni o tọ