Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 28:11-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Iṣẹ́ ọnà òkúta fínfín, bí ìfín èdìdì àmì, ni ìwọ yóò fún òkúta méjèèjì gẹ́gẹ́ bí orúkọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì: ìwọ yóò sì dè wọ́n sí ojú ìdè wúrà.

12. Ìwọ yóò sì so wọ́n pọ̀ mọ́ èjìká èfòdì náà ní òkúta ìràntí fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Árónì yóò sì máa ní orúkọ wọn ní wájú Olúwa ní èjìká rẹ̀ méjèèjì fún ìrántí.

13. Ìwọ yóò sì ṣe ojú ìdè wúrà

Ka pipe ipin Ékísódù 28