Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 27:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àgọ́ àjọ, lẹ́yìn òde láìsí aṣọ ìsélé tí ó wá níwájú ẹ̀rí náà, Árónì àti òun àti àwọn ọmọ rẹ̀, ni yóò tọ́jú rẹ̀ lati alẹ́, títí di òwúrọ̀ níwájú Olúwa: yóò sì di ìlànà láéláé ni ìrandíran wọn lọ́dọ̀ àwọn ọmọ Isírẹ́lì.

Ka pipe ipin Ékísódù 27

Wo Ékísódù 27:21 ni o tọ