Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 27:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ìhà àríwá náà jẹ́ mítà mẹ́rìndínláàdọ́ta ní gíga, kí ó sì ní aṣọ títa, pẹ̀lú ogun (20) òpó àti ogún ihò itẹ̀bọ̀ idẹ, pẹ̀lú ìkọ́ fàdákà tí ó sì di àwọn òpó mú.

Ka pipe ipin Ékísódù 27

Wo Ékísódù 27:11 ni o tọ