Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 25:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mú ojúlówó wúrà, lù ú dáradára, kí o sì fi ṣe ọ̀pá fìtílà, ìsàlẹ̀ àti apá rẹ̀, kọ́ọ̀bù rẹ̀ ti ó dàbí òdòdó, ìṣọ àti ìtànná rẹ̀ yóò jẹ́ ara kan náà pẹ̀lú rẹ̀.

Ka pipe ipin Ékísódù 25

Wo Ékísódù 25:31 ni o tọ