Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 25:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Apá àwọn kérúbù náà yóò wà ní gbígbé sókè, tí wọn yóò sì fi apá wọn se ibòòji sí orí ìtẹ́ àánú. Àwọn kérúbù náà yóò kọ ojú sí ara wọn, wọn yóò máa wo ọ̀kánkán ìtẹ́.

Ka pipe ipin Ékísódù 25

Wo Ékísódù 25:20 ni o tọ