Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 25:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa sì wí fún Mósè pé,

2. “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kí wọn mú ọrẹ wá fún mi ìwọ yóò gba ọrẹ náà fún mi ni ọwọ́ ọkùnrin kọ̀ọ̀kan ti ọkàn rẹ bá fẹ́ láti fi fún mi.

3. Wọ̀nyí ni ọrẹ ti ìwọ yóò gbà ni ọwọ́ ọ wọn: wúrà, fàdákà, idẹ,

4. aṣọ aláwọ̀ aró, aṣọ aláwọ̀ aró-fẹ́ẹ́rẹ́, aṣọ aláwọ̀ òdòdó, aṣọ funfun-láú, ìrun ewúrẹ́.

Ka pipe ipin Ékísódù 25