Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 23:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi yóò fi ìdí òpin ààlà ilẹ̀ rẹ lélẹ̀ láti etí òkun pupa títí dé òkun àwọn ara Fílístínì, láti aṣálẹ̀ títí dé etí odò Éfúrétì: Èmi yóò fa àwọn ènìyàn ti ń gbé ilẹ̀ náà lé ọ lọ́wọ́, ìwọ yóò sì lé wọn jáde kúrò ní iwájú rẹ.

Ka pipe ipin Ékísódù 23

Wo Ékísódù 23:31 ni o tọ