Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 23:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Oyún kò ní bàjẹ́ lára obìnrin kan, bẹ́ẹ̀ ni obìnrin kan kì yóò yàgàn ni ilẹ̀ rẹ. Èmi yóò fún ọ ní ẹ̀mi gígùn.

Ka pipe ipin Ékísódù 23

Wo Ékísódù 23:26 ni o tọ