Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 22:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìwọ kò gbọdọ̀ lọ́ra láti mú ọrẹ wá fún mi láti inú ire oko rẹ àti láti inú wáìnì rẹ.“Àkọ́bí ọmọ rẹ ọkùnrin ni ìwọ yóò fi fún mi.

Ka pipe ipin Ékísódù 22

Wo Ékísódù 22:29 ni o tọ