Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 22:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ìwọ bá yá ọ̀kan nínú àwọn ènìyàn mi tí ìyà ń jẹ láàrin yín lówó, má ṣe dàbí ayánilówó, kí o má sì gba èlé.

Ka pipe ipin Ékísódù 22

Wo Ékísódù 22:25 ni o tọ