Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 22:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ọkùnrin kan bá fi àrékérekè mú wúndíá kan, ẹni tí kò pinnu láti fẹ́, tí ó sì bá a lòpọ̀, yóò san owó orí rẹ̀, yóò sì fi ṣe aya rẹ̀.

Ka pipe ipin Ékísódù 22

Wo Ékísódù 22:16 ni o tọ