Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 22:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ẹnìkan bá sì yá ẹranko lọ́dọ aládúgbò rẹ̀, tí ẹranko náà sì fi ara pa, tàbí kí ó kú nígbà tí ẹni tí ó ni ín kò sí nítòòsí. O gbọdọ̀ san án padà.

Ka pipe ipin Ékísódù 22

Wo Ékísódù 22:14 ni o tọ