Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 22:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ọkùnrin kan bá jí akọ màlúù tàbí àgùntàn, tí ó sì pa á tàbí tà á. Ó gbọdọ̀ san akọ màlúù márùn ún padà fún ọ̀kan tí ó jí, àti àgùntàn mẹ́rin mìíràn fún ọ̀kan tí ó jí.

Ka pipe ipin Ékísódù 22

Wo Ékísódù 22:1 ni o tọ