Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 21:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tó lu ẹnìkejì rẹ̀ kò ní ní ẹ̀bi, níwọ̀n ìgbà ti ẹni tí a lù bá ti lè dìde, tí ó sì lé è fi ọ̀pá ìtilẹ̀ ní ọwọ rẹ̀ rìn káàkiri. Ẹni náà ni láti san owo ti ó fi tọ́jú ara rẹ̀ padà fún un, lẹ́yìn ìgbà tí ara rẹ̀ bá ti yá tan pátápátá.

Ka pipe ipin Ékísódù 21

Wo Ékísódù 21:19 ni o tọ