Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 21:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n bí kò bá mọ̀ ọ́n mọ̀ pa á, tí ó bá jẹ́ (àmúwá) ìfẹ́ Ọlọ́run ni, òun yóò lọ sí ibi tí èmi yóò yàn fún un.

Ka pipe ipin Ékísódù 21

Wo Ékísódù 21:13 ni o tọ