Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 20:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ kò gbọdọ̀ gun àkàsọ̀ lọ sí ibi pẹpẹ mi, kí àwọn ènìyàn má ba à máa wo ìhòòhò rẹ láti abẹ́ aṣọ tí ìwọ wọ̀ nígbà tí ìwọ bá ń gòkè lọ sí ibi pẹpẹ.’

Ka pipe ipin Ékísódù 20

Wo Ékísódù 20:26 ni o tọ