Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 20:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Pẹpẹ erùpẹ̀ ni kí ìwọ mọ fún mi. Ní orí pẹpẹ yìí ni kí ìwọ ti máa rú ẹbọ sísun rẹ sí mi àti ẹbọ àlàáfíà rẹ, àgùntàn rẹ, ewúrẹ́ àti akọ màlúù rẹ. Ní ibi gbogbo tí mo gbé fi ìrántí orúkọ mi sí, èmi yóò sì máa tọ̀ ọ́ wá, èmi yóò sì máa bùkún ọ níbẹ̀.

Ka pipe ipin Ékísódù 20

Wo Ékísódù 20:24 ni o tọ