Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 19:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sọ fún Mósè pé, “Èmi yóò tọ̀ ọ́ wá nínú ìkùùkuu síṣú dudu, kí àwọn ènìyàn lè gbọ́ ohùn mi nígbà ti mo bá ń bá ọ sọ̀rọ̀, kí wọn kí ó lè máa gbà ọ́ gbọ́.” Nígbà náà ni Mósè sọ ohun tí àwọn ènìyàn wí fún Olúwa.

Ka pipe ipin Ékísódù 19

Wo Ékísódù 19:9 ni o tọ