Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 19:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè wí fún Olúwa pé, “Àwọn ènìyàn kì yóò lè wá sí orí òkè Ṣínáì, nítorí ìwọ fúnrarẹ ti kìlọ̀ fún wa pé, ‘Ṣe ààlà yí òkè ká, kí o sì yà á sí mímọ́.’ ”

Ka pipe ipin Ékísódù 19

Wo Ékísódù 19:23 ni o tọ