Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 19:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ìwọ kí ó se ààlà fún àwọn ènìyàn, ibi tí wọn lè dé dúró, kí ìwọ kí ó sì wí fún wọn pé, ‘Ẹ ṣọ́ra! Ẹ má ṣe gun orí òkè lọ, kí ẹ máa tilẹ̀ fi ọwọ́ kan etí ààlà rẹ̀; ẹnikẹ́ni tí ó bá fi ọwọ́ kan òkè náà yóò kú:

Ka pipe ipin Ékísódù 19

Wo Ékísódù 19:12 ni o tọ