Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 18:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sà àwọn tí ó kún ojú òṣùwọ̀n nínú gbogbo àwọn ènìyàn: àwọn tó bẹ̀rù Ọlọ́run, ti wọ́n jẹ́ olóòótọ́, tí wọ́n kórìíra ìrẹ́jẹ: yàn wọ́n se olórí: lórí ẹgbẹ̀rún-ẹgbẹ̀rún, ọgọ́rùn-ún-ọgọ́rùn-un, àádọ́ta-àádọ́ta àti mẹ́wàá-mẹ́wàá.

Ka pipe ipin Ékísódù 18

Wo Ékísódù 18:21 ni o tọ