Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 18:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ àti àwọn ènìyàn ti ń tọ̀ ọ́ wá yìí yóò dá ara yín ní agara; iṣẹ́ yìí pọ̀ jù fún ọ, ìwọ nìkan kò lè dá a ṣe

Ka pipe ipin Ékísódù 18

Wo Ékísódù 18:18 ni o tọ