Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 17:13-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Jósúà sì fi ojú idà sẹ́gun àwọn ará Ámélékì.

14. Olúwa sì sọ fun Mósè pé. “Kọ èyí sì inú ìwé fún ìrántí, kí o sì sọ fún Jóṣúà pẹ̀lú; nítorí èmi yóò pa ìràntí Ámélékì run pátapáta kúrò lábẹ́ ọ̀run.”

15. Mósè sì tẹ́ pẹpẹ kan, ó sì sọ orúkọ pẹpẹ náà ní Olúwa ni àṣíá mi (Jóhéfà-Nisì).

16. Ó wí pé, “A gbé ọwọ́ sókè sí ìtẹ́ Olúwa. Olúwa yóò bá Ámélékì jagun láti ìran dé ìran.”

Ka pipe ipin Ékísódù 17