Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 15:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Míríámù wòlíì obìnrin, arábìnrin Árónì, mú ohun èlò orin ni ọwọ́ rẹ̀, àwọn obìnrin ti ó tẹ̀lé pẹ̀lú mú ohun èlò orin wọ́n sì ń jó.

Ka pipe ipin Ékísódù 15

Wo Ékísódù 15:20 ni o tọ