Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 14:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n àwọn ará Ísírẹ́lì la òkun kọjá lórí ìyàngbẹ ilẹ̀ pẹ̀lú ògiri omi ni ọ̀tún àti òsì wọn.

Ka pipe ipin Ékísódù 14

Wo Ékísódù 14:29 ni o tọ