Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 13:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣiṣe èyí yóò wà fún àmì ní ọwọ́ rẹ, àti bí ìránlétí ni iwájú orí rẹ tí yóò máa ran ọ létí òfin Olúwa ní ẹnu rẹ. Nítorí Olúwa mú ọ jáde láti ilẹ̀ Éjíbítì pẹ̀lú ọwọ́ agbára ńlá rẹ̀.

Ka pipe ipin Ékísódù 13

Wo Ékísódù 13:9 ni o tọ