Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 13:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè kó egungun Jósẹ́fù pẹ̀lú rẹ̀ nítorí Jósẹ́fù tí mú kí àwọn ọmọ Isírẹ́lì búra. Ó ti wí pé, “Dájúdájú Ọlọ́run yóò dìde fún ìrànlọ́wọ́ yín ẹ sì gbọdọ̀ kó egungun mi lọ pẹ̀lú yín kúrò níhìnín yìí.”

Ka pipe ipin Ékísódù 13

Wo Ékísódù 13:19 ni o tọ