Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 13:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí yóò sì jẹ́ àmì ni ọwọ́ yín àti àmì ní iwájú orí yín pé Olúwa mú wa jáde láti ilẹ̀ Éjíbítì wá pẹ̀lú ọwọ́ agbára ńlá.”

Ka pipe ipin Ékísódù 13

Wo Ékísódù 13:16 ni o tọ