Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 13:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Yóò sí ṣe ní àwọn ọjọ́ tí ń bọ̀, ní ìgbà tí àwọn ọmọ yín yóò béèrè lọ́wọ́ yín ‘Kí ni èyí túmọ̀ sí?’ Kí ìwọ kí ó sọ fún wọn pé, ‘Pẹ̀lú ọwọ́ agbára ní Olúwa fi mú wa jáde kúrò ni ilẹ̀ Éjíbítì, kúrò ní oko ẹrú.

Ka pipe ipin Ékísódù 13

Wo Ékísódù 13:14 ni o tọ