Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 10:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn yóò kún gbogbo ilé rẹ àti ilé àwọn ìjòyè rẹ àti ilé gbogbo àwọn ará Éjíbítì. Ohun ti baba rẹ tàbí baba baba rẹ kò tí ì rí láti ìgbà tí wọ́n ti wà ní ilẹ̀ náà títí di àkókò yìí.’ ” Nígbà náà ni Mósè pẹ̀yìndà kúrò níwájú Fáráò.

Ka pipe ipin Ékísódù 10

Wo Ékísódù 10:6 ni o tọ