Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 10:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Mósè gbé ọwọ́ rẹ sókè sí ojú ọ̀run, òkùnkùn biribiri sì bo gbogbo ilẹ̀ Éjíbítì fún ọjọ́ mẹ́ta. Ṣùgbọ́n àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní ìmọ́lẹ̀ ní ibi tí wọn ń gbé.

Ka pipe ipin Ékísódù 10

Wo Ékísódù 10:22 ni o tọ