Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 10:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ̀n bo gbogbo ilẹ̀ tí ilẹ̀ fi di dúdú. Wọ́n ba gbogbo ohun tó kù ní orí ilẹ̀ lẹ́yìn òjò yìnyín jẹ́; gbogbo ohun ọ̀gbìn tí ó wà ní inú oko àti gbogbo èso tí ó wà lórí igi. Kò sí ewe tí ó kù lórí igi tàbí lorí ohun ọ̀gbìn ní gbogbo ilẹ̀ Íjibítì.

Ka pipe ipin Ékísódù 10

Wo Ékísódù 10:15 ni o tọ