Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 1:2-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

2. Rúbẹ́nì, Símónì, Léfì àti Júdà,

3. Ísákárì, Ṣébúlúnì àti Bẹ́ńjámínì,

4. Dánì àti Náfítalì, Gádì àti Ásérì.

5. Àwọn ìran Jákọ́bù sì jẹ́ àádọ́rin ní àpapọ̀; Jóṣẹ́fù sì ti wà ní Éjíbítì.

6. Wáyìí o, Jóṣẹ́fù àti gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀ àti gbogbo ìran náà kú,

7. Ṣùgbọ́n àwọn ará Ísírẹ́lì ń bí sí i, wọ́n ń pọ̀ sí i gidigidi, wọ́n kò sì ní òǹkà tí ó fi jẹ́ pé wọ́n kún ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Ékísódù 1