Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 1:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a lo ọgbọ́n àlùmọ̀kọ́rọ́yí láti dá wọn lẹ́kun, bí kò ṣe bẹ́ẹ̀ wọn yóò túbọ̀ máa pọ̀ sí i. Bí ogun bá sì bẹ́ sílẹ̀, wọn yóò darapọ̀ mọ́ àwọn ọ̀tá wa, wọn yóò sì da ojú ìjà kọ wá, wọn yóò sì sá àsálà kúrò ní ilẹ̀ yìí.”

Ka pipe ipin Ékísódù 1

Wo Ékísódù 1:10 ni o tọ