Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 1:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ìwọ̀nyí ni àwọn orúkọ ọmọ Ísírẹ́lì tí wọ́n bá Jákọ́bù lọ sí Éjíbítì, ẹnìkọ̀ọ̀kan pẹ̀lú ìdílé rẹ̀:

2. Rúbẹ́nì, Símónì, Léfì àti Júdà,

3. Ísákárì, Ṣébúlúnì àti Bẹ́ńjámínì,

Ka pipe ipin Ékísódù 1