Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 6:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ iwájú, bí ọmọ rẹ bá béèrè pé, “Kí ni ìtumọ̀ àwọn àṣẹ, ìlànà àti òfin wọ̀nyí tí Olúwa Ọlọ́run wa ti pàṣẹ fún ọ?”

Ka pipe ipin Deutarónómì 6

Wo Deutarónómì 6:20 ni o tọ