Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 4:40-42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

40. Ẹ pa àwọn ìlànà àti àṣẹ rẹ̀ mọ́ tí mo ń fún un yín lónìí; kí ó ba à le è yẹ yín, kí ẹ̀yin sì le è pẹ́ ní ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run yín fún un yín ní gbogbo ìgbà.

41. Mósè sì ya àwọn ìlú mẹ́ta kan sọ́tọ̀ ní apá ìwọ̀ oòrùn Jọ́dánì.

42. Níbi tí ẹnikẹ́ni tí ó bá pa ènìyàn le sálọ, bí ó bá ṣe pé ó ṣèèṣì pa aládúgbò rẹ̀ láìsí ìkùnsínú láàrin wọn. Òun le sálọ sí èyíkéyìí nínú ìlú mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wọ̀nyí, fún ìgbàlà ẹ̀mí ara rẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 4