Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 4:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo pe ọ̀run àti ayé láti jẹ́rìí takò yín lónìí, pé kíákíá ni ẹ ó parun ní ilẹ̀ náà tí ẹ ń la Jọ́dánì kọjá lọ láti gbà. Ẹ kò ní pẹ́ ní ilẹ̀ náà, ṣùgbọ́n ẹ̀yin yóò run pátapáta.

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:26 ni o tọ