Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 4:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ má ṣe fi kún àwọn ohun tí mo pàṣẹ fún un yín, ẹ kò sì gbọdọ̀ yọ kúrò nínú wọn, Ṣùgbọ́n ẹ pa òfin Olúwa Ọlọ́run yín tí mo fún un yín mọ́.

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:2 ni o tọ