Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 32:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé báyìí ni ẹ̀yin yóò ṣe san an fún Olúwa,Áà ẹ̀yin aṣiwèrè àti aláìgbọ́n ènìyàn?Ǹjẹ́ òun kọ́ ni baba yín, Ẹlẹ́dàá yín,tí ó dá a yín tí ó sì mọ yín?

Ka pipe ipin Deutarónómì 32

Wo Deutarónómì 32:6 ni o tọ