Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 32:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni àpáta, iṣẹ́ ẹ rẹ̀ jẹ́ pípé,gbogbo ọ̀nà an rẹ̀ jẹ́ òdodo.Ọlọ́run olótìítọ́ tí kò ṣe àsìṣe kan,Ó dúró ṣinṣin, òdodo àti òtítọ́ ni òun.

Ka pipe ipin Deutarónómì 32

Wo Deutarónómì 32:4 ni o tọ