Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 31:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti nígbà tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpọ́njú àti ìṣòro bá wá sórí i wọn, orin yìí yóò jẹ́ ẹ̀rí sí wọn, nítorí kò ní di ìgbàgbé fún àwọn ọmọ wọn. Mo mọ̀ ohun tí wọ́n ní inú dídùn sí láti ṣe, pàápàá kí èmi tó mú wọn wá sí ilẹ̀ tí mo ṣe ìlérí fún wọn lórí ìbúra.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 31

Wo Deutarónómì 31:21 ni o tọ